November 6-12
ÁMÓSÌ 1-9
- Orin 144 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Wá Jèhófà, Kí O sì Máa Wà Láàyè Nìṣó”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ámósì.] 
- Amo 5:4, 6—A gbọ́dọ̀ mọ Jèhófà kí a sì máa ṣe ìfẹ́ rẹ̀ (w04 11/15 24 ¶20) 
- Amo 5:14, 15—A gbọ́dọ̀ fara mọ́ àwọn ìlànà Jèhófà nípa ohun tó tọ́ àtohun tí kò tọ́, ká sì nífẹ̀ẹ́ àwọn ìlànà náà (jd 90-91 ¶16-17) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Amo 2:12—Báwo ni a ṣe lè fi ẹ̀kọ́ tó wà nínú ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí sílò lónìí? (w07 10/1 14 ¶8) 
- Amo 8:1, 2—Kí ni “apẹ̀rẹ̀ èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn kan” dúró fún? (w07 10/1 14 ¶6) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Amo 4:1-13 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Ṣe Ìpadàbẹ̀wò”: (15 min.) Ìjíròrò. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò àwọn akéde méjì tó ń ṣe ìpadàbẹ̀wò, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr “Apá 7—Àwọn Ìlérí Ìjọba Ọlọ́run—Ó Ń Sọ Ohun Gbogbo Di Ọ̀tun,” orí 21 ¶1-7 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 128 àti Àdúrà