ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 November ojú ìwé 5
  • November 20-26

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 20-26
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 November ojú ìwé 5

November 20-26

MÍKÀ 1-7

  • Orin 26 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Kí Ni Jèhófà Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Míkà.]

    • Mik 6:​6, 7​—Tí a kò bá hùwà tó dáa sí àwọn èèyàn, Jèhófà kò ní tẹ́wọ́ gba àwọn ẹbọ wa (w08 5/15 6 ¶20)

    • Mik 6:8​—Àwọn ohun tí Jèhófà ń béèrè lọ́wọ́ wa kò ju agbára wa lọ (w12 11/1 22 ¶4-7)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mik 2:12​—Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe ṣẹ? (w07 11/1 15 ¶6)

    • Mik 7:7​—Kí nìdí tó fi yẹ ká “fi ẹ̀mí ìdúródeni hàn” sí Jèhófà? (w03 8/15 24 ¶20)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mik 4:​1-10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 83:18​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 3:14​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 123-124 ¶20-21.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 106

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (6 min.)

  • Jèhófà Fẹ́ Ká Jẹ́ Ọ̀làwọ́ (Òwe 3:27): (9 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò yìí.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 21 ¶15-20, àtẹ ìsọfúnni “Àwọn Ohun Tí Yóò Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Iwájú,” àpótí tó wà fún àtúnyẹ̀wò “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 132 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́