December 11-17
SEKARÁYÀ 1-8
Orin 146 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
‘Di Aṣọ Ọkùnrin Tó Jẹ́ Júù Mú’: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sekaráyà.]
Sek 8:20-22—Àwọn èèyàn láti inú gbogbo èdè àti orílẹ̀-èdè ńwá ojúure Jèhófà (w14 11/15 27 ¶14)
Sek 8:23—Àwọn tó ní ìrètí láti wà lórí ilẹ̀ ayé ńfi tinútinú tọ àwọn ẹni àmì òróró lẹ́yìn, wọ́n sì ń ṣètìlẹ́yìn fún wọn (w16.01 21 ¶4; w09 2/15 27 ¶14)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Sek 5:6-11—Bí ìwà ibi tilẹ̀ kún inú ayé lónìí, kí ló yẹ kó jẹ́ ìpinnu wa? (w17.10 25 ¶18)
Sek 6:1—Kí ni àwọn òkè ńlá bàbà méjì náà dúró fún? (w17.10 27-28 ¶7-8)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣura tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sek 8:14-23
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.6—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g17.6—Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé ìròyìn yìí. Ṣe ìpadàbẹ̀wò, kó o sì jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 5 ¶1-2.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Wàásù fún Gbogbo Èèyàn ní Ìpínlẹ̀ Ìwàásù Rẹ”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Wíwàásù ní “Apá Ibi Jíjìnnà Jù Lọ ní Ilẹ̀ Ayé”.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 22 ¶17-24, àpótí tó wà fún àtúnyẹ̀wò lójú ìwé 240
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3min.)
Orin 134 àti Àdúrà