December 18-24
SEKARÁYÀ 9-14
Orin 49 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Dúró sí ‘Àfonífojì Àwọn Òkè Ńlá’”: (10 min.)
Sek 14:3,4—“Àfonífojì ńlá” náà dúró fún ààbò Ọlọ́run (w13 2/15 19 ¶10)
Sek 14:5—Jèhófà máa dáàbò bo àwọn tó “sá lọ sí àfonífojì” náà tí wọ́n sì dúró síbẹ̀ (w13 2/15 20 ¶13)
Sek 14:6, 7,12,15—Àwọn tí kò sí lábẹ́ ààbò Ọlọ́run máa pa run (w13 2/15 20 ¶15)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Sek 12:3—Ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà “sọ Jerúsálẹ́mù di òkúta ẹrù ìnira”? (w07 12/15 23 ¶9-10)
Sek 12:7—Báwo ni Jèhófà ṣe máa “kọ́kọ́ gba àgọ́ Júdà là”? (w07 12/15 25 ¶13)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sek 12:1-14
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g17.6 14-15—Pe ẹni náà wá sáwọn ìpàdéwa.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g17.6 —Ojú ìwé 14 àti 15 lẹ jíròrò nínú ìwé ìròyìn yìí nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà. Ṣe ìpadàbẹ̀wò, kó o sì pe ẹni náà wá sáwọn ìpàdéwa.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 5—Pe ẹni náà wá sáwọn ìpàdéwa.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù December.
“Ohun Tuntun Táá Máa Wáyé ní Ìpàdé Àárín Ọ̀sẹ̀”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Bẹtifágè, Òkè Ólífì, àti Jerúsálẹ́mù.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv ọ̀rọ̀ ìṣáájú tó wà lójú ìwé 3 àti orí 1 ¶1-9
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3min.)
Orin 5 àti Àdúrà