December 25-31
MÁLÁKÌ 1-4
- Orin 36 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ṣé Ìgbéyàwó Rẹ Ń Múnú Jèhófà Dùn?”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Málákì.] 
- Mal 2:13,14—Jèhófà kórìíra kéèyàn máa ṣe àdàkàdekè nínú ìgbéyàwó (jd 125-126 ¶4-5) 
- Mal 2:15,16—Jẹ́ olóòótọ́ sí ọkọ tàbí aya rẹ (w02 5/1 18 ¶19) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Mal 1:10—Kí nìdí tó fi yẹ kó jẹ́ pé ìfẹ́ aláìmọtara-ẹni-nìkan tá a ní fún Ọlọ́run àti fún àwọn èèyàn ló ńmú ká jọ́sìn Ọlọ́run? (w07 12/15 27¶1) 
- Mal 3:1—Báwo ni ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe nímùúṣẹ ní ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní àti lákòókò yìí? (w13 7/15 10-11 ¶5-6) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mal 1:1-10 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Kọ 15:26—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 26:19; 2Kọ 1:3,4—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. (Wo mwb16.08 8 ¶2.) 
- Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w07 12/15 28 ¶1—Àkòrí: Báwo La Ṣe Lè Kó Gbogbo Ìdá Mẹ́wàá Wa Wá Sínú Ilé Ìtọ́jú Nǹkan Pa Mọ́ Lónìí? 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?”: (15 min.) Ìbéèrè àti ìdáhùn. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 1 ¶10-18, àpótí tó wà lójú ìwé 13 [Kò pọn dandan kẹ́ ẹ jíròrò àpótí tàbí àfikún àlàyé] 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3min.) 
- Orin 114 àti Àdúrà