March 5-11
MÁTÍÙ 20-21
- Orin 76 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ẹnì Yòówù Tí Ó Bá Fẹ́ Di Ẹni Ńlá Láàárín Yín Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Òjíṣẹ́ Yín”: (10 min.) - Mt 20:3—Àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn Farisí onígbèéraga fẹ́ràn káwọn èèyàn máa kí wọn “ní ibi ọjà” (“Ibi Ọjà” àwòrán àti fídíò lórí Mt 20:3, nwtsty) 
- Mt 20:20, 21—Àwọn àpọ́sítélì méjì béèrè fún ipò ọlá àti ipò àṣẹ (“ìyá àwọn ọmọkùnrin Sébédè,” “ọ̀kan ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ àti ọ̀kan ní òsì rẹ” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 20:20, 21, nwtsty) 
- Mt 20:25-28—Jésù sọ pé ó yẹ kí àwọn ọmọ ẹ̀yìn òun jẹ́ òjíṣẹ́ tó nírẹ̀lẹ̀ (“òjíṣẹ́,” “kì í ṣe kí a lè ṣe ìránṣẹ́ fún un, bí kò ṣe kí ó lè ṣe ìránṣẹ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 20:26, 28, nwtsty) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Mt 21:9—Nígbà táwọn èrò kígbe pé: “Gba Ọmọkùnrin Dáfídì là, ni àwa bẹ̀bẹ̀!” kí ni wọ́n ní lọ́kàn? (“Gbà là, ni àwa bẹ̀bẹ̀,” “Ọmọkùnrin Dáfídì” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 21:9, nwtsty) 
- Mt 21:18, 19—Kí nìdí tí Jésù fi sọ fún igi ọ̀pọ̀tọ́ náà pé kó rọ? (jy 244 ¶4-6) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 20:1-19 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Wo Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 36-37 ¶3-4 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.) 
- Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù March. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv àfikún àlàyé Ìgbà Wo Ló Yẹ Kí Obìnrin Máa Borí, Kí sì Nìdí? 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 53 àti Àdúrà