May 7-13
MÁÀKÙ 7-8
- Orin 13 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Gbé Òpó Igi Oró Rẹ, Kí Ó sì Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn”: (10 min.) - Mk 8:34—Ká tó lè tẹ̀ lé Kristi, a gbọ́dọ̀ sẹ́ níní ara wa (“kí ó sẹ́ níní ara rẹ̀” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 8:34 nwtsty; w92 8/1 17 ¶14) 
- Mk 8:35-37—Jésù béèrè àwọn ìbéèrè méjì tó ń múni ronú jinlẹ̀ tó máa jẹ́ ká mọ ohun tó yẹ ká fi sípò àkọ́kọ́ nígbèésí ayé wa (w08 10/15 25-26 ¶3-4) 
- Mk 8:38—A nílò ìgboyà tá a bá fẹ́ tẹ̀ lé Kristi (jy 143 ¶4) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Mk 7:5-8—Kí ló dé táwọn Farisí fi ranrí mọ́ ọ̀rọ̀ fífọ ọwọ́? (w16.08 30 ¶1-4) 
- Mk 7:32-35—Báwo ni bí Jésù ṣe fi ẹ̀mí ìgbatẹnirò hàn sí ọkùnrin adití náà ṣe jẹ́ àpẹẹrẹ fún wa? (w00 2/15 17-18 ¶9-11) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mk 7:1-15 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Wo Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 157-158 ¶9-10 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.) 
- “Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Tẹ̀ Lé Kristi”: (10 min.) Ìjíròrò. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 7 ¶10-19 àti àpótí Ṣé Mo Ka Ẹ̀jẹ̀ Sí Ohun Mímọ́? [A máa jíròrò àfikún àlàyé tó wà nínú àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé lọ́sẹ̀ míì] 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 60 àti Àdúrà