May 21-27
Máàkù 11-12
- Orin 34 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ó Fi Púpọ̀ Sí I Ju Àwọn Tó Kù Lọ”: (10 min.) - Mk 12:41, 42—Jésù ṣàkíyèsí òtòṣì opó kan tó ń sọ ẹyọ owó kéékèèké méjì, tí ìníyelórí wọn kéré gan-an sínú àpótí ìṣúra tó wà nínú tẹ́ńpìlì (“àwọn àpótí ìṣúra,” “ẹyọ owó kéékèèké méjì,” “tí ìníyelórí wọ́n kéré gan-an” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 12:41, 42, nwtsty) 
- Mk 12:43—Jésù mọyì ohun tí obìnrin náà ṣe, ó sì tẹnu mọ́ kókó yìí fún àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ (w97 10/15 16-17 ¶16-17) 
- Mk 12:44—Ọrẹ tí obìnrin opó yìí ṣe níye lórí gan-an lójú Jèhófà (w97 10/15 17 ¶17; w87 12/1 30 ¶1; cl 185 ¶15) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Mk 11:17—Kí nìdí tí Jésù fi pe tẹ́ńpìlì ní “ilé àdúrà fún gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè”? (“ilé àdúrà fún gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 11:17, nwtsty) 
- Mk 11:27, 28—“Nǹkan” wo làwọn alátakò Jésù ń tọ́ka sí? (jy 244 ¶7) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mk 12:13-27 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Dáhùn ìbéèrè kan táwọn èèyàn sábà máa ń béèrè tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù ní ìpínlẹ̀ yín. 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ẹni náà sọ fún ẹ pé èèyàn òun kan kú láìpẹ́ yìí. 
- Ìpadàbẹ̀wò Kejì Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ìgbàgbọ́ Nínú Jèhófà Ń Mú Ká Ṣàṣeyọrí: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv àfikún Àwọn Ìpín Tó Tara Èròjà Ẹ̀jẹ̀ Wá, Àtàwọn Ọ̀nà Kan Tí Wọ́n Ń Gbà Ṣiṣẹ́ Abẹ 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 98 àti Àdúrà