May 28–June 3
MÁÀKÙ 13-14
- Orin 55 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìbẹ̀rù Èèyàn Dẹkùn Mú Ẹ”: (10 min.) - Mk 14:29, 31—Kì í ṣe pé àwọn àpọ́sítélì fẹ́ kọ Jésù sílẹ̀ 
- Mk 14:50—Nígbà tí wọ́n mú Jésù, gbogbo àwọn àpọ́sítélì pa Jésù tì, wọ́n sì sá lọ 
- Mk 14:47, 54, 66-72—Pétérù nígboyà láti gbèjà Jésù, ó tẹ̀ lé e ní òkèèrè réré, àmọ́ nígbà tó yá, ó da Jésù ní ìgbà mẹ́ta (ia 200 ¶14; it-2 619 ¶6) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Mk 14:51, 52—Ta ló ṣeé ṣe kí ọ̀dọ́kùnrin tó sá lọ ní ìhòòhò náà jẹ́? (w08 2/15 30 ¶6) 
- Mk 14:60-62—Kí ló ṣeé ṣe kó jẹ́ ìdí tí Jésù fi dáhùn ìbéèrè àlùfáà àgbà náà? (jy 287 ¶4) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mk 14:43-59 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé. 
- Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó o máa lò. Fi ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ lọ̀ ọ́. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 171-172 ¶17-18 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Jèhófà Á Jẹ́ Kó O Nígboyà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 8 ¶1-10 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 81 àti Àdúrà