ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 August ojú ìwé 6
  • August 27–September 2

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • August 27–September 2
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 August ojú ìwé 6

August 27–September 2

Lúùkù 23-24

  • Orin 130 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ṣe Tán Láti Dárí Jini”: (10 min.)

    • Lk 23:34​—Jésù dárí ji àwọn ọmọ ogun tó kàn án mọ́gi (cl 297 ¶16)

    • Lk 23:43​—Jésù dárí ji ọ̀daràn kan (g 4/08 11 ¶5-6)

    • Lk 24:34​—Jésù dárí ji Pétérù (cl 297-298 ¶17-18)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Lk 23:31​—Kí ló ṣeé ṣe kí Jésù máa tọ́ka sí nínú ẹsẹ Bíbélì yìí? (“nígbà tí igi wà ní tútù, . . . nígbà tí ó bá rọ” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 23:31, nwtsty)

    • Lk 23:33​—Àwọn nǹkan wo làwọn awalẹ̀pìtàn rí tó jẹ́ ká gbà pé ó ṣeé ṣe kí wọ́n máa fi ìṣó kan àwọn tí wọ́n bá fẹ́ pa mọ́gi? (“Ìṣó nínú Egungun Gìgísẹ̀” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 23:33, àwòrán àti fídíò nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lk 23:​1-16

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó bá ipò rẹ̀ mu èyí tó wà nínú Àwọn Ohun Tá A Fi Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Bíbélì tó o máa lò, fi ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ lọ̀ ọ́.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 4 ¶3-4

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 20

  • “Jésù Kú fún Àwọn Arákùnrin Rẹ Náà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Máa Sunwọ̀n Sí i Lójoojúmọ́!

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 12 ¶1-8

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 82 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́