December 10-16
ÌṢE 12-14
- Orin 60 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Bánábà àti Pọ́ọ̀lù Sọ Àwọn Èèyàn Tó Wà Láwọn Ọ̀nà Jíjìn Di Ọmọlẹ́yìn”: (10 min.) - Iṣe 13:2, 3—Jèhófà yan Bánábà àti Sọ́ọ̀lù fún iṣẹ́ pàtàkì kan (bt 86 ¶4) 
- Iṣe 13:12, 48; 14:1—Iṣẹ́ àṣekára tí wọ́n ṣe mú èso jáde (bt 95 ¶5) 
- Iṣe 14:21, 22—Bánábà àti Sọ́ọ̀lù fún àwọn ọmọlẹ́yìn tuntun níṣìírí (w14 9/15 13 ¶4-5) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Iṣe 12:21-23—Kí la rí kọ́ látinú ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Hẹ́rọ́dù? (w08 5/15 32 ¶7) 
- Iṣe 13:9—Kí nìdí tí wọ́n tún ń pe Sọ́ọ̀lù ní Pọ́ọ̀lù? (“Sọ́ọ̀lù, ẹni tí ó tún ń jẹ́ Pọ́ọ̀lù” àti “Pọ́ọ̀lù” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 13:9, nwtsty) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 12:1-17 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bt 79 ¶8-9—Àkòrí: Máa Gbàdúrà Fún Àwọn Tá A Jọ Jẹ́ Onígbàgbọ́. 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Ran Àwọn Tó Ní ‘Ìtẹ̀sí-Ọkàn Títọ́’ Lọ́wọ́ Láti Di Ọmọlẹ́yìn”: (15 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò náà Jèhófà Ọlọ́run Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 17 ¶1-10 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 55 àti Àdúrà