January 21-27
ÌṢE 25-26
- Orin 73 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Pọ́ọ̀lù Ké Gbàjarè sí Késárì Ó sì Wàásù fún Ọba Hẹ́rọ́dù Àgírípà”: (10 min.) - Iṣe 25:11—Pọ́ọ̀lù lo ẹ̀tọ́ tó ní láti ké gbàjarè sí Késárì (bt 198 ¶6) 
- Iṣe 26:1-3—Pọ́ọ̀lù fọgbọ́n gbèjà òtítọ́ lọ́nà tó dára níwájú Ọba Hẹ́rọ́dù Àgírípà (bt 198-201 ¶10-16) 
- Iṣe 26:28—Ìwàásù Pọ́ọ̀lù wọ ọba lọ́kàn (bt 202 ¶18) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Iṣe 26:14—Kí ni ọ̀pá kẹ́sẹ́? (“títàpá sí ọ̀pá kẹ́sẹ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 26:14, nwtsty; “Ọ̀pá Kẹ́sẹ́” nwtstg) 
- Iṣe 26:27—Kí nìdí tó fi ṣòro fún Ọba Àgírípà láti fèsì nígbà tí Pọ́ọ̀lù béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ bóyá ó gba àwọn wòlíì gbọ́? (w03 11/15 16-17 ¶14) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 25:1-12 (th ẹ̀kọ́ 5) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 2) 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Fi ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni han onílé. (th ẹ̀kọ́ 3) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Òfin Fìdí Iṣẹ́ Wa Múlẹ̀ ní Quebec”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 2 ¶1-9 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 122 àti Àdúrà