January 28–February 3
ÌṢE 27-28
- Orin 129 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Pọ́ọ̀lù Wọkọ̀ Ojú Omi Lọ sí Róòmù”: (10 min.) - Iṣe 27:23, 24—Áńgẹ́lì kan sọ fún Pọ́ọ̀lù pé òun àtàwọn tó wà nínú ọkọ̀ ojú omi máa gúnlẹ̀ láyọ̀ (bt 208 ¶15) 
- Iṣe 28:1, 2—Ọkọ̀ ojú omi tí Pọ́ọ̀lù wọ̀ rì sí erékùṣù Málítà (bt 209 ¶18; 210 ¶21) 
- Iṣe 28:16, 17—Pọ́ọ̀lù dé Róòmù láyọ̀ (bt 213 ¶10) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Iṣe 27:9—Kí ni “ààwẹ̀ [ọjọ́ ètùtù]”? (“ààwẹ̀ [ọjọ́ ètùtù]” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 27:9, nwtsty) 
- Iṣe 28:11—Kí ló gbàfiyèsí nípa ère tó wà lórí ọkọ̀ yẹn? (“Àwọn Ọmọ Súúsì” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 28:11, nwtsty) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 27:1-12 (th ẹ̀kọ́ 5) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 2) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 139 ¶16-17 (th ẹ̀kọ́ 3) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Pọ́ọ̀lù Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Ọlọ́run Ó sì Mọ́kànle”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà “Irin Ni A fi Ń Pọ́n Irin”—Àyọlò. Rọ àwọn ará pé kí wọ́n lọ wo gbogbo fídíò náà látòkèdélẹ̀. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 2 ¶10-16 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 93 àti Àdúrà