March 4-10
RÓÒMÙ 12-14
- Orin 106 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ohun Tó Túmọ̀ Sí Láti Fi Ìfẹ́ Hàn Síra Wa”: (10 min.) 
- Ro 12:17-19—Tẹ́nì kan bá ṣẹ̀ wá, ká má gbẹ̀san (w09 10/15 8 ¶3; w07 7/1 24-25 ¶12-13) 
- Ro 12:20, 21—Fi ire ṣẹ́gun ibi (w12 11/15 29 ¶13) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Ro 12:1—Kí ni ẹsẹ yìí túmọ̀ sí? (lv 64 ¶5-6) 
- Ro 13:1—Ọ̀nà wo ni a gbà gbé àwọn aláṣẹ onípò gíga “dúró sí àwọn ipò wọn aláàlà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run”? (w08 6/15 31 ¶4) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ro 13:1-14 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Lo Ìbéèrè Bó Ṣe Yẹ, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 3 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni. 
- Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w11 9/1 21-22—Àkòrí: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Káwa Kristẹni Máa San Owó Orí Tí Wọn Bá Tiẹ̀ Ń Fi Owó Yẹn Ṣe Àwọn Nǹkan Tí Kò Tọ́? (th ẹ̀kọ́ 3) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 3 ¶13-20 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 57 àti Àdúrà