March 18-24
1 KỌ́RÍŃTÌ 1-3
- Orin 127 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ṣé Ẹni Tara Ni Ẹ́ Tàbí Ẹni Tẹ̀mí?”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Kọ́ríńtì Kìíní.] 
- 1Kọ 2:14—Kí ló túmọ̀ sí pé kéèyàn jẹ́ “ènìyàn ti ara”? (w18.02 19 ¶4-5) 
- 1Kọ 2:15, 16—Kí ló túmọ̀ sí pé kéèyàn jẹ́ “ènìyàn ti ẹ̀mí”? (w18.02 19 ¶6; 22 ¶15) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - 1Kọ 1:20—Báwo ni Ọlọ́run ṣe “sọ ọgbọ́n ayé di òmùgọ̀”? (it-2 1193 ¶1) 
- 1Kọ 2:3-5—Báwo ni àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù ṣe lè ràn wá lọ́wọ́? (w08 7/15 27 ¶6) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Kọ 1:1-17 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 3) 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Fi ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni han onílé. (th ẹ̀kọ́ 11) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Bó O Ṣe Lè Kọ Lẹ́tà”: (8 min.) Ìjíròrò. 
- A Máa Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Pe Àwọn Èèyàn sí Ìrántí Ikú Kristi ní Saturday, March 23: (7 min.) Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó apá yìí. Fún ẹnì kọ̀ọ̀kan ní ìwé ìkésíni náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a máa lò. Sọ ètò tí ìjọ ṣe láti kárí ìpínlẹ̀ ìwàásù yín. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 4 ¶1-9 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 51 àti Àdúrà