April 29–May 5
2 KỌ́RÍŃTÌ 1-3
- Orin 44 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Jèhófà—‘Ọlọ́run Ìtùnú Gbogbo’”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Kọ́ríńtì Kejì.] 
- 2Kọ 1:3—“Baba àánú oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́” ni Jèhófà (w17.07 13 ¶4) 
- 2Kọ 1:4—Ìtùnú tí Jèhófà pèsè la fi ń tu àwọn míì nínú (w17.07 15 ¶14) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - 2Kọ 1:22—Kí ni “àmì ìdánilójú” àti “èdìdì” tí àwọn ẹni àmì òróró kọ̀ọ̀kan gbà lọ́dọ̀ Ọlọ́run? (w16.04-E 32) 
- 2Kọ 2:14-16—Kí ló ṣeé ṣe kí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ní lọ́kàn nígbà tó sọ̀rọ̀ nípa “ìjáde àwọn tó ń yọ ayọ̀ ìṣẹ́gun”? (w10 8/1 23) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 2Kọ 3:1-18 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 48 ¶3-4 (th ẹ̀kọ́ 8) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Ẹ̀kọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ni Kó O Máa Lé”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Ẹ̀kọ́ Jèhófà Sọ Wá Di Ọlọ́rọ̀ Nípa Tẹ̀mí. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 5 ¶14-20 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 130 àti Àdúrà