June 3-9
GÁLÁTÍÀ 4-6
- Orin 16 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “ ‘Àkàwé’ Kan àti Ìtumọ̀ Rẹ̀”: (10 min.) - Ga 4:24, 25—Hágárì dúró fún orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì tó wà lábẹ́ Májẹ̀mú Òfin (it-1 1018 ¶2) 
- Ga 4:26, 27—Sárà dúró fún “Jerúsálẹ́mù ti òkè,” ìyẹn apá ti òkè ọ̀run lára ètò Jèhófà (w14 10/15 10 ¶11) 
- Ga 4:28-31—“Ọmọ” Jerúsálẹ́mù ti òkè máa bù kún àwọn tó bá jẹ́ onígbọràn 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Ga 4:6—Kí ni ọ̀rọ̀ Hébérù tàbí Árámáíkì náà ábà túmọ̀ sí? (w09 4/1 13) 
- Ga 6:17—Kí ló ṣeé ṣe kí “àpá ẹrú Jésù” tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ pé ó wà lára òun túmọ̀ sí? (w10 11/1 15) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ga 4:1-20 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Jẹ́ Kí Ìdí Tó O Fi Ka Ìwé Mímọ́ Ṣe Kedere, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 6 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni. 
- Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w12 3/15 30-31—Àkòrí: Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí Kristẹni Kan Wo Àwòrán Ìṣekúṣe Rárá? (th ẹ̀kọ́ 13) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.) 
- Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 6 ¶14-20 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 40 àti Àdúrà