June 17-23
ÉFÉSÙ 4-6
- Orin 71 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ẹ Gbé Gbogbo Ìhámọ́ra Ogun Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wọ̀”: (10 min.) - Ef 6:11-13—A nílò ààbò kúrò lọ́wọ́ Sátánì àtàwọn ẹ̀mí èṣù rẹ̀ (w18.05 27 ¶1) 
- Ef 6:14, 15—Fi òtítọ́, òdodo àti ìhìn rere àlàáfíà dáàbò bo ara rẹ (w18.05 28-29 ¶4, 7, 10) 
- Ef 6:16, 17—Fi ìgbàgbọ́, ìrètí ìgbàlà àti Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run dáàbò bo ara rẹ (w18.05 29-31 ¶13, 16, 20) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Ef 4:30—Báwo lẹnì kan ṣe lè kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run? (it-1 1128 ¶3) 
- Ef 5:5—Kí nìdí tá a fi lè sọ pé abọ̀rìṣà ni ẹni tó bá jẹ́ olójúkòkòrò? (it-1 1006 ¶2) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ef 4:17-32 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6) 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? lẹ́yìn náà, kẹ́ ẹ jíròrò rẹ̀. (th ẹ̀kọ́ 8) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Kí Ni Jèhófà Máa Fẹ́ Kí N Ṣe?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ẹ Máa Fi Òye Mọ Ohun Tí Ìfẹ́ Jèhófà Jẹ́ (Le 19:18). 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 7 ¶9-15 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 34 àti Àdúrà