July 22-28
1 TÍMÓTÌ 1-3
- Orin 103 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Iṣẹ́ Rere Ni Kó O Máa Lé”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Tímótì Kìíní.] 
- 1Ti 3:1—Bíbélì gba àwọn arákùnrin níyànjú pé kí wọ́n sapá láti di alábòójútó (w16.08 21 ¶3) 
- 1Ti 3:13—Àwọn arákùnrin tó ń ṣiṣẹ́ lọ́nà tó dáa máa gba ọ̀pọ̀ ìbùkún (km 12/79 3 ¶7) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - 1Ti 1:4—Kí nìdí tí Pọ́ọ̀lù fi kìlọ̀ fún Tímótì pé kó má tẹ́tí sí àwọn ìtàn ìdílé? (it-1 914-915) 
- 1Ti 1:17—Kí nìdí tó fi jẹ́ pé Jèhófà nìkan la lè pè ní “Ọba ayérayé”? (cl 12 ¶15) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Ti 2:1-15 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 2) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 38-39 ¶6-7 (th ẹ̀kọ́ 6) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ṣiṣẹ́ ní Warwick Bọlá fún Jèhófà: (6 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà (lára àwọn fídíò tó wà ní abala IṢẸ́ WA). Lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí: - Báwo ni àwọn ọ̀dọ́ Ẹlẹ́rìí ṣe ṣèrànwọ́ nígbà tá à ń kọ́ Bẹ́tẹ́lì tó wà ní Warwick, àǹfààní wo ni wọ́n sì rí níbẹ̀? - Àwọn àǹfààní wo làwọn ọ̀dọ́kùnrin àtàwọn ọ̀dọ́bìnrin tó wà nínú ìjọ ní láti fi bọlá fún Jèhófà? 
- “Ẹ̀kọ́ Wo Lo Rí Kọ́ Lára Wọn?”: (9 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Bọ̀wọ̀ Fún Àwọn Ọkùnrin Onírìírí. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 8 ¶16-22 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 115 àti Àdúrà