July 29–August 4
1 TÍMÓTÌ 4-6
Orin 80 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ìfọkànsin Ọlọ́run Tàbí Ọrọ̀”: (10 min.)
1Ti 6:6-8—Èrè tó wà nínú “ìfọkànsin Ọlọ́run [pẹ̀lú] ìtẹ́lọ́rùn” (w03 6/1 9 ¶1-2)
1Ti 6:9—Ohun tó máa ń yọrí sí téèyàn bá pinnu láti di ọlọ́rọ̀ (g 7/07 28 ¶1)
1Ti 6:10—Ìrora tí ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ owó máa ń ní (g 1/09 6 ¶4-6)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
1Ti 4:2—Báwo lẹnì kan ṣe lè dá àpá sí ẹ̀rí ọkàn rẹ̀, kí sì nìdí tí èyí fi léwu? (lv 21-22 ¶17)
1Ti 4:13 àlàyé ìsàlẹ̀—Kí nìdí tí Pọ́ọ̀lù fi gba Tímótì níyànjú láti máa tẹra mọ́ kíkàwé ní gbangba? (it-2 714 ¶1-2)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Ti 4:1-16 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé. (th ẹ̀kọ́ 11)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 181-182 ¶20-21 (th ẹ̀kọ́ 3)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Fọgbọ́n fòpin sí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tí kò méso jáde.—Wo mwb19.02 7. (th ẹ̀kọ́ 12)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tí Ìfẹ́ Ọrọ̀ Máa Ń Fà: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà A Gbọ́dọ̀ ‘Fi Ìfaradà Sáré’—Fi Àwọn Ẹrù Tí Kò Pọndandan Sílẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ tó wà níbẹ̀.
“Ìfọkànsin Ọlọ́run Tàbí Eré Ìdárayá”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò eré ojú pátákó náà Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Eré Ìdárayá.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 8 ¶23 àti àfikún Ọdún 1914—Ọdún Pàtàkì Nínú Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 21 àti Àdúrà