August 5-11
2 TÍMÓTÌ 1-4
- Orin 150 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ọlọ́run Kò Fún Wa Ní Ẹ̀mí Ojo”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Tímótì Kejì.] 
- 2Ti 1:7—Tí ìṣòro bá dé, ro “àròjinlẹ̀” (w09 5/15 15 ¶9) 
- 2Ti 1:8—Má ṣe tijú ìhìn rere (w03 3/1 9 ¶7) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - 2Ti 2:3, 4—Kí la lè ṣe tá ò fi ní “tara bọ òwò ṣíṣe” jù? (w17.07 10 ¶13) 
- 2Ti 2:23—Kí ni ohun kan tá a lè ṣe tá ò fi ní “dá sí àwọn ìjiyàn tí kò bọ́gbọ́n mu àti ti àìmọ̀kan”? (w14 7/15 14 ¶10) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 2Ti 1:1-18 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Àpèjúwe Tó Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 8 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni. 
- Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w14 7/15 13 ¶3-7—Àkòrí: Báwo Làwọn Èèyàn Jèhófà Ṣe Lè “Kọ Àìṣòdodo Sílẹ̀ Pátápátá”? (th ẹ̀kọ́ 7) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Máa Kẹ́gbẹ́ Pẹ̀lú Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Pinnu Láti Kọ Ẹgbẹ́ Búburú Sílẹ̀ Lákọ̀tán. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 9 ¶1-3 àti àfikún Ta Ni Máíkẹ́lì Olú-Áńgẹ́lì? 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 126 àti Àdúrà