ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 August ojú ìwé 7
  • August 26–September 1

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • August 26–September 1
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 August ojú ìwé 7

August 26–September 1

HÉBÉRÙ 4-6

  • Orin 5 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Sa Gbogbo Ipá Rẹ Kó O Lè Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run”: (10 min.)

    • Heb 4:1, 4​—Mọ ọjọ́ ìsinmi Ọlọ́run (w11 7/15 24-25 ¶3-5)

    • Heb 4:6​—Máa ṣègbọràn sí Jèhófà (w11 7/15 25 ¶6)

    • Heb 4:9-11​—A ò gbọdọ̀ máa ṣe ohun tó wù wá nígbà gbogbo (w11 7/15 28 ¶16-17)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Heb 4:12​—Kí ni “ọ̀rọ̀ Ọlọ́run” nínú àyíká ọ̀rọ̀ yìí? (w16.09 13)

    • Heb 6:17, 18​—Kí ni “àwọn nǹkan méjì tí kò lè yí pa dà” tí ẹsẹ yìí mẹ́nu kàn? (it-1 1139 ¶2)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Heb 5:1-14 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 198-199 ¶7-8 (th ẹ̀kọ́ 12)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 75

  • “Àwọn Iṣẹ́ Rere Tá Ò Ní Gbàgbé”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Ohun Tó O Lè Ṣe Láti Ṣiṣẹ́ Sìn Ní Bẹ́tẹ́lì.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh 9 ¶16-18

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 12 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́