September 30–October 6
JÉMÍÌSÌ 1-2
Orin 122 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ohun Tó Ń Fa Ẹ̀ṣẹ̀ àti Ikú”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jémíìsì.]
Jem 1:14—Èròkerò máa ń mú kí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ jọba lọ́kàn ẹni (g17.4 14)
Jem 1:15—Ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ máa ń mú kéèyàn dẹ́ṣẹ̀, ìyẹn sì máa yọrí sí ikú (g17.4 14)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Jem 1:17—Kí nìdí tí Bíbélì fi pe Jèhófà ní “Baba àwọn ìmọ́lẹ̀ àtọ̀runwá”? (it-2 253-254)
Jem 2:8—Kí ni “ọba òfin” náà? (it-2 222 ¶4)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. ) Jem 2:10-26 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó o máa lò. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé. (th ẹ̀kọ́ 3)
Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó o máa lò. Fi ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ lọ̀ ọ́. (th ẹ̀kọ́ 12)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 28-29 ¶4-5 (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ẹ Máa Ronú Lórí Àwọn Nǹkan Yìí”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, Yẹra fún Ohun Tó Lè Ba Ìdúróṣinṣin Rẹ Jẹ́—Eré Ìnàjú Tí Kò Bójú Mu.
Ẹ̀yin Òbí—Ẹ Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Kí Wọ́n Lè Yẹra fún Fífi Ọ̀rọ̀ Ìṣekúṣe Ránṣẹ́ Lórí Fóònù: (7 min.) Alàgbà ni kó sọ àsọyé yìí, a mú u jáde látinú Jí! January-February 2014 ojú ìwé 4 àti 5
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 11 ¶1-6
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 130 àti Àdúrà