October 7-13
JÉMÍÌSÌ 3–5
Orin 50 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Máa Fi Ọgbọ́n Ọlọ́run Ṣèwà Hù”: (10 min.)
Jem 3:17—Ọgbọ́n Ọlọ́run jẹ́ mímọ́, ó sì lẹ́mìí àlàáfíà (cl 221-222 ¶9-10)
Jem 3:17—Ọgbọ́n Ọlọ́run máa ń fòye báni lò, ó ṣe tán láti ṣègbọràn, ó máa ń ṣàánú gan-an, ó sì ń so èso rere (cl 223-224 ¶12; 224-225 ¶14-15)
Jem 3:17—Ọgbọ́n Ọlọ́run kì í ṣe ojúsàájú, kì í sì í ṣe àgàbàgebè (cl 226-227 ¶18-19)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Jem 4:5—Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wo ni Jémíìsì ń tọ́ka sí níbí? (w08 11/15 20 ¶6)
Jem 4:11,12—Ọ̀nà wo lẹni tó bá ń “sọ̀rọ̀ tí kò dáa nípa arákùnrin kan” ṣe ń sọ̀rọ̀ “tí kò dáa nípa òfin”? (w97 11/15 20-21 ¶8)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jem 3:1-18 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Yí Ohùn Pa Dà Bó Ṣe Yẹ, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 10 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.
Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w10 9/1 23-24—Àkòrí: Kí nìdí tó fi yẹ ká jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ta ló sì yẹ ká jẹ́wọ́ fún? (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 11 ¶7-11
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 125 àti Àdúrà