October 21-27
1 PÉTÉRÙ 3-5
- Orin 14 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Òpin Ohun Gbogbo Ti Sún Mọ́lé”: (10 min.) - 1Pe 4:7—“Ẹ máa ronú jinlẹ̀, kí ẹ sì wà lójúfò, kí ẹ lè máa gbàdúrà” (w13 11/15 3 ¶1) 
- 1Pe 4:8—“Ẹ ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ fún ara yín” (w99 4/15 22 ¶3) 
- 1Pe 4:9—“Ẹ máa ṣe ara yín lálejò láìráhùn” (w18.03 14-15 ¶2-3) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - 1Pe 3:19, 20—Ìgbà wo ni Jésù wàásù fún “àwọn ẹ̀mí tó wà lẹ́wọ̀n,” báwo ló sì ṣe ṣe é? (w13 6/15 23) 
- 1Pe 4:6—Àwọn wo ni “òkú” tá a “kéde ìhìn rere” fún? (w08 11/15 21 ¶8) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Pe 3:8-22 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6) 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? lẹ́yìn náà, kẹ́ ẹ jíròrò rẹ̀. (th ẹ̀kọ́ 8) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Ìwà Mímọ́ àti Ọ̀wọ̀ Tó Jinlẹ̀ Máa Ń Yíni Lọ́kàn Pa Dà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Jèhófà Ń Fún Wa Lókun Ká Lè Gbé Ẹrù Wa. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 11 ¶19-21 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 61 àti Àdúrà