November 4-10
1 JÒHÁNÙ 1-5
- Orin 122 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ẹ Má Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Ayé Tàbí Àwọn Nǹkan Tó Wà Nínú Ayé”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jòhánù Kìíní.] 
- 1Jo 2:15, 16—‘Gbogbo ohun tó wà nínú ayé wá látọ̀dọ̀ ayé,’ kì í ṣe látọ̀dọ̀ Baba (w05 1/1 10 ¶13) 
- 1Jo 2:17—Ayé àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ rẹ̀ ń kọjá lọ (w13 8/15 27 ¶18) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - 1Jo 2:7, 8—Báwo ni àṣẹ tí Jòhánù tọ́ka sí ṣe jẹ́ àṣẹ àtijọ́, tó sì tún jẹ́ tuntun? (w13 9/15 10 ¶14) 
- 1Jo 5:16, 17—Kí ni ‘ẹ̀ṣẹ̀ tó yẹ fún ikú’? (it-1 862 ¶5) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Jo 1:1–2:6 (th ẹ̀kọ́ 5) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Ìtara, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 11 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni. 
- Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w04 10/1 29—Àkòrí: Bó ṣe wà nínú 1 Jòhánù 4:18, kí ni Jòhánù ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé “ìfẹ́ tó pé máa ń lé ìbẹ̀rù jáde”? (th ẹ̀kọ́ 7) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Yẹra fún Ẹ̀mí Ayé Tó O Bá Ń Ṣètò Ìgbéyàwó”: (15 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Ìgbéyàwó Tó Ní Ọlá Lójú Jèhófà. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 12 ¶10-16 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 118 àti Àdúrà