November 11-17
2 JÒHÁNÙ 1-13; 3 JÒHÁNÙ 1-14–JÚÙDÙ 1-25
- Orin 128 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “A Gbọ́dọ̀ Jà Fitafita Ká Lè Dúró Nínú Òtítọ́”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jòhánù Kejì.] 
- [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jòhánù Kẹta.] 
- [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Júùdù.] 
- Jud 3—“Ẹ máa jà fitafita torí ìgbàgbọ́” (w04 9/15 11-12 ¶8-9) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Jud 4, 12—Báwo làwọn aláìṣèfẹ́ Ọlọ́run tó yọ́ wọnú ìjọ ṣe dà bí ‘àpáta tó fara pa mọ́ lábẹ́ omi níbi àsè tí a fìfẹ́ pè’? (it-2 279, 816) 
- Jud 14, 15—Kí nìdí tí Énọ́kù fi sọ àsọtẹ́lẹ̀ yìí bí ohun tó ti ṣẹlẹ̀ kọjá, báwo sì ni àsọtẹ́lẹ̀ náà ṣe ṣẹ? (wp17.1 12 ¶1, 3) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 2Jo 1-13 (th ẹ̀kọ́ 12) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 1) 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 6) 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Kó o wá fún un ní káàdì ìkànnì JW.ORG. (th ẹ̀kọ́ 1) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 12 ¶17-19 àti àpótí Kòrìíra Àwọn Ohun Tí Jèhófà Kórìíra 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 147 àti Àdúrà