December 2-8
ÌFIHÀN 7-9
- Orin 63 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Jèhófà Bù Kún Ogunlọ́gọ̀ Èèyàn Tí Ẹnikẹ́ni Kò Lè Kà”: (10 min.) - Ifi 7:9—“Ogunlọ́gọ̀ èèyàn” náà dúró níwájú ìtẹ́ Jèhófà (it-1 997 ¶1) 
- Ifi 7:14—Ogunlọ́gọ̀ èèyàn náà máa la “ìpọ́njú ńlá” já (it-2 1127 ¶4) 
- Ifi 7:15-17—Lọ́jọ́ iwájú, ogunlọ́gọ̀ èèyàn náà máa gbádùn ìbùkún lórí ilẹ̀ ayé (it-1 996-997) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ifi 7:1-12 (th ẹ̀kọ́ 5) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Ọ̀yàyà àti Ìfọ̀rọ̀rora-Ẹni-Wò, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 12 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni. 
- Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w16.01 25-26 ¶12-16—Àkòrí: Kí nìdí tí kò fi yẹ ká máa da ara wa láàmú bí àwọn tó ń jẹ búrẹ́dì tí wọ́n sì ń mu wáìnì níbi Ìrántí Ikú Kristi bá ń pọ̀ sí i? (th ẹ̀kọ́ 6) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.) 
- Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù December. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 13 ¶5-9 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 27 àti Àdúrà