ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 December ojú ìwé 3
  • December 9-15

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 9-15
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 December ojú ìwé 3

December 9-15

ÌFIHÀN 10-12

  • Orin 26 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Wọ́n Pa ‘Àwọn Ẹlẹ́rìí Méjì,’ àmọ́ Wọ́n Pa Dà Wà Láàyè”: (10 min.)

    • Ifi 11:3​—‘Àwọn ẹlẹ́rìí méjì’ náà fi ọ̀tàlélẹ́gbẹ̀fà (1,260) ọjọ́ sọ tẹ́lẹ̀ (w14 11/⁠15 30)

    • Ifi 11:7​—“Ẹranko tó jáde látinú ọ̀gbun àìnísàlẹ̀” pa wọ́n

    • Ifi 11:11​—Ọlọ́run jí ‘àwọn ẹlẹ́rìí méjì’ náà dìde lẹ́yìn “ọjọ́ mẹ́ta àtààbọ̀”

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ifi 10:9, 10​—Báwo ni àkájọ ìwé tí wọ́n fún Jòhánù ṣe “korò,” tó sì tún “dùn”? (it-2 880-881)

    • Ifi 12:1-5​—Báwo làwọn ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe ṣẹ? (it-2 187 ¶7-9)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ifi 10:1-11 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́​—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Wàásù lọ́nà àìjẹ́-bí-àṣà lọ́nà tó bá ìpínlẹ̀ yín mu. (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Lẹ́yìn náà, fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 9)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 148

  • “Ilẹ̀ Gbé Odò Náà Mì”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Wọ́n Dá Àwọn Ará Wa Sílẹ̀ Lẹ́wọ̀n ní Korea.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 13 ¶10-16

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 47 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́