ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 December ojú ìwé 4
  • December 16-22

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 16-22
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 December ojú ìwé 4

December 16-22

ÌFIHÀN 13-16

  • Orin 55 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Má Ṣe Bẹ̀rù Àwọn Ẹranko Abàmì Náà”: (10 min.)

    • Ifi 13:1, 2​—Dírágónì náà fún ẹranko olórí méje àti oníwo mẹ́wàá náà ní ọlá àṣẹ (w12 6/15 8 ¶6)

    • Ifi 13:11, 15​—Ẹranko oníwo méjì náà mí èémí ìyè sínú ère ẹranko àkọ́kọ́ (re 193 ¶26; 194-195 ¶30-31)

    • Ifi 13:16, 17​—Má ṣe gba àmì ẹranko náà (w09 2/15 4 ¶2)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ifi 16:13, 14​—Kí ló máa mú káwọn ọba gbogbo ilẹ̀ ayé kóra jọ fún “ogun ọjọ́ ńlá Ọlọ́run Olódùmarè”? (w09 2/15 4 ¶5)

    • Ifi 16:21​—Kí làwa èèyàn Jèhófà á máa kéde tó bá kù díẹ̀ kí ayé Sátánì pa run? (w15 7/15 16 ¶9)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ifi 16:1-16 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 2)

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Lẹ́yìn náà, ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 11)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 21

  • Má Ṣe Dá Sọ́rọ̀ Ogun àti Òṣèlú: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Má Ṣe Dá Sọ́rọ̀ Ogun àti Òṣèlú Nínú Èrò àti Ìṣe Rẹ. Lẹ́yìn náà béèrè pé, kí la lè ṣe tá ò fi ní dá sọ́rọ̀ òṣèlú tàbí àwọn rògbòdìyàn tó ń ṣẹlẹ̀ láwùjọ? Ẹ tún wo fídíò Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà Tó O Bá Wà Níbi Tí Wọ́n Ti Ń Kí Àsíá. Lẹ́yìn náà, béèrè pé, báwo la ṣe lè múra sílẹ̀ fáwọn ipò tó lè fẹ́ mú ká lọ́wọ́ sí ọ̀rọ̀ òṣèlú?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 13 ¶17-19

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 131 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́