FEBRUARY 24–MARCH 1
JẸ́NẸ́SÍSÌ 20-21
- Orin 108 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Gbogbo Ìgbà Ni Jèhófà Máa Ń Mú Àwọn Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ”: (10 min.) - Jẹ 21:1-3—Sérà lóyún ó sì bí ọmọkùnrin kan (wp17.5 14-15) 
- Jẹ 21:5-7—Jèhófà ṣe ohun tó dà bíi pé kò ṣeé ṣe 
- Jẹ 21:10-12, 14—Ábúráhámù àti Sérà nígbàgbọ́ tó lágbára nínú ìlérí tí Jèhófà ṣe nípa Ísákì 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.) - Jẹ 20:12—Báwo ni Sérà ṣe jẹ́ àbúrò Ábúráhámù? (wp17.3 12, àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé) 
- Jẹ 21:33—Báwo ni Ábúráhámù ṣe ké pe “orúkọ Jèhófà”? (w89 7/1 20 ¶9) 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 20:1-18 (th ẹ̀kọ́ 5) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Báwo ni akéde yẹn ṣe jẹ́ kí onílé rí ìdí tó fi ka ẹsẹ Ìwé Mímọ́ náà? Báwo ni ìpadàbẹ̀wò tí akéde yẹn ṣe ṣe jẹ́ àpẹẹrẹ tó dáa? 
- Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 4) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 35 ¶19-20 (th ẹ̀kọ́ 3) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn Ọdọọdún: (15 min.) Alàgbà ni kó sọ àsọyé yìí. Kọ́kọ́ ka lẹ́tà látọ̀dọ̀ ẹ̀ka ọ́fíìsì nípa ìròyìn iṣẹ́ ìsìn ọdọọdún, lẹ́yìn náà fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu àwọn akéde kan tó o ti yàn, kí wọ́n sọ àwọn ìrírí tó ń gbéni ró tí wọ́n ní lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù ní ọdún iṣẹ́ ìsìn tó kọjá. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 16 ¶9-10 àti àfikún Ṣé Oṣù December Ni Wọ́n Bí Jésù? 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
- Orin 119 àti Àdúrà