ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 October ojú ìwé 2
  • October 5-11

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 5-11
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 October ojú ìwé 2

October 5-11

Ẹ́KÍSÓDÙ 31-32

  • Orin 45 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹ Sá fún Ìbọ̀rìṣà”: (10 min.)

    • Ẹk 32:1​—Ti pé nǹkan ò rọrùn ò túmọ̀ sí pé ó yẹ ká máa sin ọlọ́run míì (w09 5/15 11 ¶11)

    • Ẹk 32:​4-6​—Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń sin ọlọ́run míì, àmọ́ wọ́n gbà pé ìjọsìn tòótọ́ làwọn ń ṣe (w12 10/15 25 ¶12)

    • Ẹk 32:​9, 10​—Jèhófà bínú sáwọn ọmọ Ísírẹ́lì (w18.07 20 ¶14)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Ẹk 31:17​—Kí ló túmọ̀ sí pé Jèhófà sinmi ní ọjọ́ keje? (w19.12 3 ¶4)

    • Ẹk 32:​32, 33​—Báwo la ṣe mọ̀ pé ẹ̀kọ́ èké ni èrò táwọn kan ní pé “ìgbàlà lẹ́ẹ̀kan, ìgbàlà gbogbo ìgbà”? (w87 9/1 29)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 32:​15-35 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè pé: Báwo ni Jọkẹ́ ṣe lo ìbéèrè lọ́nà tó yẹ? Báwo ló ṣe múra ọkàn onílé sílẹ̀ fún ìpadàbẹ̀wò?

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 9)

  • Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w10 5/15 21​—Àkòrí: Kí Nìdí Tí Jèhófà Ò Ṣe Fìyà Jẹ Áárónì Torí Pé Ó Ṣe Ère Ọmọ Màlúù? (th ẹ̀kọ́ 7)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 36

  • “Mọyì Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Jèhófà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Má Ṣe Jẹ́ Kí Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Jèhófà Bà Jẹ́ (Kol. 3:5).

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jy orí 135

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 90 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́