October 12-18
Ẹ́KÍSÓDÙ 33-34
- Orin 115 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Àwọn Ànímọ́ Jèhófà Tó Fani Mọ́ra”: (10 min.) - Ẹk 34:5—Téèyàn bá mọ ohun tí orúkọ Ọlọ́run túmọ̀ sí, á mọ ohun tó fẹ́ ṣe, ohun tó ń ṣe àtàwọn ànímọ́ rẹ̀ (it-2 466-467) 
- Ẹk 34:6—Àwọn ànímọ́ Jèhófà ń mú ká sún mọ́ ọn (w09 5/1 18 ¶3-5) 
- Ẹk 34:7—Jèhófà máa ń dárí ji ẹlẹ́ṣẹ̀ tó bá ronú pìwà dà (w09 5/1 18 ¶6) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.) - Ẹk 33:11, 20—Báwo ni Ọlọ́run ṣe bá Mósè sọ̀rọ̀ ní “ojúkojú”? (w04 3/15 27 ¶5) 
- Ẹk 34:23, 24—Kí nìdí táwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì fí nílò ìgbàgbọ́ kí wọ́n tó lè máa pàdé lẹ́ẹ̀mẹta lọ́dún? (w98 9/1 20 ¶5) 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 33:1-16 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. E wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè pé: Báwo ni Jọkẹ́ ṣe ṣàlàyé ẹsẹ Bíbélì kó lè fa ẹ̀kọ́ ibẹ̀ yọ? Kí ni Jọkẹ́ ṣe kí onílé lè ronú jinlẹ̀? 
- Ìpadàbẹ̀wò: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 16) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà fún onílé ní ìwé Bíbélì Kọ́ Wa, kó o sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ ní orí 2. (th ẹ̀kọ́ 8) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ṣé Jèhófà Ni Ọ̀rẹ́ Tẹ́ Ẹ Fẹ́ràn Jù Lọ?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—‘Ẹ Tọ́ Jèhófà Wò, Kí Ẹ sì Rí I Pé Ó Jẹ́ Ẹni Rere’. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jy orí 136 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
- Orin 103 àti Àdúrà