October 19-25
Ẹ́KÍSÓDÙ 35-36
- Orin 92 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Jèhófà Ràn Wọ́n Lọ́wọ́ Láti Ṣe Iṣẹ́ Rẹ̀”: (10 min.) - Ẹk 35:25, 26—Jèhófà máa ń bù kún àwọn tó bá múra tán láti ṣe iṣẹ́ rẹ̀ (w14 12/15 4 ¶4) 
- Ẹk 35:30-35—Ẹ̀mí mímọ ran Bẹ́sálẹ́lì àti Òhólíábù lọ́wọ́ kí wọ́n lè ṣe “onírúurú iṣẹ́” (w11 12/15 18 ¶6) 
- Ẹk 36:1, 2—Jèhófà ló ràn wọ́n lọ́wọ́ láti ṣe iṣẹ́ náà (w11 12/15 19 ¶7) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.) - Ẹk 35:1-3—Kí la lè rí kọ́ nípa bí Jèhófà ṣe fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lófin nípa Sábáàtì? (w05 5/15 23 ¶14) 
- Ẹk 35:21—Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nípa bí wọ́n ṣe jẹ́ ọ̀làwọ́? (w00 11/1 29 ¶1) 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 35:1-24 (th ẹ̀kọ́ 11) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 11) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Sọ fún onílé pé kó lọ sórí ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 4) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 26 ¶18-20 (th ẹ̀kọ́ 19) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ìròyìn Ìgbìmọ̀ Ìṣèwéjáde ti Ọdún 2018: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà béèrè pé: Àwọn àyípadà wo la ti ṣe sí bá a ṣe ń tẹ ìwé jáde, kí sì nìdí tá a fi ṣe bẹ́ẹ̀? Kí ni àbájáde àwọn àyípadà yìí? Báwo ni iṣẹ́ ìtúmọ̀ èdè ṣe ń mú kí ọ̀pọ̀ èèyàn túbọ̀ rí oúnjẹ tẹ̀mí? Àwọn ìbùkún wo là ń rí bá a ṣe ń gbé àwọn ìtẹ̀jáde wa sórí ìkànnì? 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jy orí 137 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
- Orin 69 àti Àdúrà