December 21-27
LÉFÍTÍKÙ 14-15
Orin 122 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ìjọsìn Mímọ́ Gba Pé Kéèyàn Wà ní Mímọ́”: (10 min.)
Le 15:13-15—Àwọn ọkùnrin gbọ́dọ̀ wẹ ara wọn mọ́ (it-1 263)
Le 15:28-30—Àwọn obìnrin gbọ́dọ̀ wẹ ara wọn mọ́ (it-2 372 ¶2)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Le 14:14, 17, 25, 28—Kí la rí kọ́ látinú ohun tí ẹni tó ní àrùn ẹ̀tẹ̀ gbọ́dọ̀ ṣe kó tó lè wà ní mímọ́? (it-1 665 ¶5)
Le 14:43-45—Kí ni òfin tó wà nípa ilé tó ní àrùn ẹ̀tẹ̀ tó le gan-an kọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nípa Jèhófà? (g 1/06 14, àpótí)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Le 14:1-18 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ìtẹ̀jáde tó dáhùn ìbéèrè kan tó béèrè. (th ẹ̀kọ́ 16)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ṣe bíi pé o fi fídíò Ta Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà? han onílé, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 11)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 11 ¶6-7 (th ẹ̀kọ́ 19)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Máa Lo Àwọn Ìwé Ìròyìn Wa”: (10 min.) Ìjíròrò.
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù December.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) rr orí 2 ¶10-18
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 118 àti Àdúrà