January 11-17
LÉFÍTÍKÙ 20-21
- Orin 80 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Yàtọ̀”: (10 min.) 
- Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.) 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Le 20:1-13 (th ẹ̀kọ́ 5) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ìpadàbẹ̀wò: Àdúrà—1Jo 5:14. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 6) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ìwé Ìròyìn Ayọ̀, kó o sì fi ẹ̀kọ́ 12 bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 19) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Ṣe Ohun Tá Jẹ́ Kí Ìgbéyàwó Rẹ Lágbára Sí I”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà A Gbọ́dọ̀ ‘Fi Ìfaradà Sáré’—Máa Tẹ̀ Lé Òfin Eré Sísá. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr apá 1, orí 3 ¶1-10, fídíò ohun tó wà ní orí 3 àti àpótí 3A 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 94 àti Àdúrà