January 25-31
LÉFÍTÍKÙ 24-25
- Orin 144 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ọdún Júbílì Ṣàpẹẹrẹ Òmìnira Ọjọ́ Iwájú”: (10 min.) 
- Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.) - Le 24:20—Ṣé ohun tí ẹsẹ yìí ń sọ ni pé Ọlọ́run fẹ́ ká máa gbẹ̀san? (w09 9/1 22 ¶4) 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Le 24:1-23 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 16) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé, kó o sì ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 11) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) fg ẹ̀kọ́ 12 ¶6-7 (th ẹ̀kọ́ 14) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.) 
- “Ọlọ́run àti Kristi Jẹ́ Kí Òmìnira Ọjọ́ Iwájú Ṣeé Ṣe”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Bí Ìjì Bá Ń Jà, Jésù Ni Kó O Tẹjú Mọ́!—Àpẹẹrẹ Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Ọjọ́ Ọ̀la. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 3 ¶21-30 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 104 àti Àdúrà