February 1-7
LÉFÍTÍKÙ 26-27
- Orin 89 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Bá A Ṣe Lè Rí Ìbùkún Jèhófà”: (10 min.) 
- Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.) 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Le 26:18-33 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ, kó o sì fún onílé ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 11) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 6) 
- Àsọyé: (5 min.) w09 8/1 30—Àkòrí: Èló Ni Kí N Fi Ṣètọrẹ fún Iṣẹ́ Ọlọ́run? (th ẹ̀kọ́ 16) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Pinnu Láti Sin Jèhófà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Bó O Ṣe Lè Ṣèrìbọmi. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 4 ¶1-9, fídíò ohun tó wà ní orí 4 àti àpótí 4A 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 2 àti Àdúrà