ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 March ojú ìwé 6
  • March 22-28

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 22-28
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 March ojú ìwé 6

March 22-28

NỌ́ŃBÀ 13-14

  • Orin 118 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Bí Ìgbàgbọ́ Ṣe Lè Jẹ́ Ká Nígboyà”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Nọ 13:27​—Kí làwọn amí yẹn sọ tó yẹ kó jẹ́ káwọn ọmọ Ísírẹ́lì túbọ̀ nígbàgbọ́ nínú Jèhófà? (Le 20:24; it-1 740)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 13:​1-20 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Àsọyé: (5 min.) w15 9/15 14-16 ¶8-12​—Àkòrí: Àwọn Ìbéèrè Tó Máa Jẹ́ Ká Mọ̀ Bóyá Ìgbàgbọ́ Wa Ṣì Lágbára. (th ẹ̀kọ́ 14)

  • “Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Máa Lo Ìbéèrè”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Túbọ̀ Já Fáfá​—Máa Lo Ìbéèrè.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 73

  • Ìdí Tí Àwa Kristẹni Tòótọ́ Fi Nílò Ìgboyà​—Láti Wàásù: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Ìṣòro wo ni Kitty Kelly ní? Kí ló ràn án lọ́wọ́ láti ní ìgboyà? Àwọn ìbùkún wo ni Kitty Kelly rí torí pé ó nígboyà?

  • Ìdí Tí Àwa Kristẹni Tòótọ́ Fi Nílò Ìgboyà​—Láti Má Ṣe Dá Sí Ọ̀rọ̀ Òṣèlú: (7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Àwọn ìṣòro wo ni Arákùnrin Ayenge Nsilu kojú? Àwọn nǹkan wo ni wọ́n ṣe kí wọ́n lè túbọ̀ nígboyà? Àwọn nǹkan wo ni Arákùnrin Ayenge fi sọ́kàn tó jẹ́ kí wọ́n túbọ̀ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 6 ¶14-19

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 143 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́