March 29–April 4
NỌ́ŃBÀ 15-16
- Orin 101 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Má Ṣe Máa Gbéra Ga, Má sì Dá Ara Rẹ Lójú Jù”: (10 min.) 
- Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.) - Nọ 15:32-35—Kí la rí kọ́ látinú ẹsẹ Bíbélì yìí? (w98 9/1 20 ¶1-2) 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 15:1-16 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Jésù—Mt 16:16. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ. 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 1) 
- Àsọyé: (5 min.) w15 5/15 14 ¶5-6—Àkòrí: Ìyàtọ̀ Wo Ló Wà Nínú Kéèyàn Máa Yangàn àti Kéèyàn Máa Gbéra Ga? (th ẹ̀kọ́ 8) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Má Ṣe Fara Wé Àwọn Aláìdúróṣinṣin”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Má Ṣe Fara Wé Àwọn Aláìdúróṣinṣin. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 7 ¶1-7 àti fídíò ohun tó wà ní orí 7 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 126 àti Àdúrà