April 19-25
NỌ́ŃBÀ 22-24
- Orin 8 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Jèhófà Sọ Ègún Di Ìbùkún”: (10 min.) 
- Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.) - Nọ 22:20-22—Kí nìdí tí Jèhófà fi bínú sí Báláámù? (w04 8/1 27 ¶3) 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 23:11-26 (th ẹ̀kọ́ 2) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- “Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Máa Lo Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Túbọ̀ Já Fáfá—Jẹ́ Kí Àwọn Èèyàn Rí Agbára Tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ní. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) fg ẹ̀kọ́ 5 ¶3-4 (th ẹ̀kọ́ 6) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Jèhófà Máa Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ Ká Lè Wàásù Lójú Àtakò”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò A Gbọ́rọ̀ Látẹnu Arákùnrin Dmitriy Mikhaylov. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 7 ¶24-30 àti àpótí 7B 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 21 àti Àdúrà