June 14-20
DIUTARÓNÓMÌ 5-6
- Orin 134 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà”: (10 min.) 
- Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.) - Di 5:21—Kí ni òfin tí Jèhófà ṣe lórí ojúkòkòrò kọ́ wa? (w19.02 22 ¶11) 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 5:1-21 (th ẹ̀kọ́ 5) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ ẹni náà, kó o sì ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 9) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Sọ ohun tó máa bá ipò onílé mu, kó o sì ka ẹsẹ Bíbélì tó máa wọ̀ ọ́ lọ́kàn. (th ẹ̀kọ́ 12) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) fg ẹ̀kọ́ 9 ¶6-7 (th ẹ̀kọ́ 8) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Máa Fìfẹ́ Hàn Nínú Ìdílé”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Máa Fi Ìfẹ́ Ti Kì Í Yẹ̀ Hàn Nínú Ìdílé. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 9 ¶27-32, àpótí 9D àti 9E 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 111 àti Àdúrà