ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 July ojú ìwé 2
  • July 5-11

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • July 5-11
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 July ojú ìwé 2

July 5-11

DIUTARÓNÓMÌ 11-12

  • Orin 40 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Bí Jèhófà Ṣe Fẹ́ Ká Máa Sin Òun”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Di 11:29​—Ìgbà wo ló ṣeé ṣe kí ẹsẹ yìí nímùúṣẹ, kí ló sì ṣẹlẹ̀ nígbà yẹn? (it-1 925-926)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 11:1-12 (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • “Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Máa Fọ̀rọ̀ Ro Ara Ẹ Wò”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Túbọ̀ Já Fáfá​—Máa Fọ̀rọ̀ Ro Ara Ẹ Wò.

  • Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Ìyà​—Jem 1:13. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 1)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 103

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 10 ¶8-12 àti àpótí 10A

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 72 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́