July 19-25
DIUTARÓNÓMÌ 16-18
Orin 115 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Béèyàn Ṣe Lè Dájọ́ Lọ́nà Tó Tọ́”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 16:9-22 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún ẹni náà ní ìtẹ̀jáde tó dáhùn ìbéèrè kan tó béèrè. (th ẹ̀kọ́ 3)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún ẹni náà ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 4)
Àsọyé: (5 min.) it-1 519 ¶4—Àkòrí: Ṣé Àwọn Tó Ń Dájọ́ Wà Nínú Ìjọ Kristẹni? (th ẹ̀kọ́ 18)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ṣé Ó Wù Ẹ́ Láti Ṣe Iṣẹ́ Aṣáájú Ọ̀nà Déédéé?: (10 min.) Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó apá yìí, wo Ìwé Ìpàdé July 2016 ní apá “Ṣé O Lè Gbìyànjú Rẹ̀ Wò fún Ọdún Kan?” àti “Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Iṣẹ́ Ìsìn Aṣáájú-Ọ̀nà Déédéé.” Ẹ wo fídíò Jèhófà Ti Iṣẹ́ Ìwàásù Wa Lẹ́yìn, kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 11 ¶1-8 àti fídíò ohun tó wà ní orí 11
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 60 àti Àdúrà