August 2-8
DIUTARÓNÓMÌ 22-23
- Orin 1 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Òfin Tí Jèhófà Ṣe Nípa Àwọn Ẹranko Fi Hàn Pé Wọ́n Ṣe Pàtàkì Sí I”: (10 min.) 
- Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.) - Di 23:19, 20—Kí nìdí táwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi lè gba èlé lọ́wọ́ àjèjì, àmọ́ tí wọn ò lè gbà á lọ́wọ́ ọmọ Ísírẹ́lì bíi tiwọn? (it-1 600) 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 23:1-14 (th ẹ̀kọ́ 5) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- “Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Wọni Lọ́kàn”: (9 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Túbọ̀ Já Fáfá—Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Wọni Lọ́kàn. 
- Àsọyé: (5 min.) g 5/15 15—Àkòrí: Ṣé Ó Burú Láti Pa Àwọn Ẹranko? (th ẹ̀kọ́ 14) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 11 ¶18-26 àti àpótí 11A 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 77 àti Àdúrà