ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 July ojú ìwé 15
  • August 30–September 5

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • August 30–September 5
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 July ojú ìwé 15

August 30–September 5

DIUTARÓNÓMÌ 31-32

  • Orin 78 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ohun Tí Àpèjúwe Tó Wà Nínú Orin Onímìísí Kan Kọ́ Wa”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Di 31:12​—Báwo làwọn òbí ṣe lè fi ìlànà yìí sílò? (w04 9/15 27 ¶11)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 32:36-52 (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Sọ ohun tó máa bá ipò onílé mu, kó o sì ka ẹsẹ Bíbélì tó máa wọ̀ ọ́ lọ́kàn. (th ẹ̀kọ́ 12)

  • Àsọyé: (5 min.) w07 5/15 15-16​—Àkòrí: Àwọn Ọmọ Rẹ Ń Wò Ẹ́! (th ẹ̀kọ́ 16)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 25

  • Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àpẹẹrẹ Àwọn Tó Ń Múpò Iwájú: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò ‘Ẹ Máa Rántí Àwọn Tó Ń Mú Ipò Iwájú’ (Heb 13:7). Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará pé: Kí la rí kọ́ látinú àpẹẹrẹ T. J. Sullivan? George Gangas? Karl Klein? Daniel Sydlik?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 13 ¶1-6 àti fídíò ohun tó wà ní orí 13

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 128 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́