October 25-31
JÓṢÚÀ 15-17
- Orin 146 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Dáàbò Bo Ogún Iyebíye Tí Jèhófà Fún Ẹ”: (10 min.) 
- Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.) - Joṣ 17:15, 18—Báwo la ṣe mọ̀ pé igbó kìjikìji pọ̀ nílẹ̀ Ísírẹ́lì àtijọ́? (w15 7/15 32) 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Joṣ 15:1-12 (th ẹ̀kọ́ 5) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Pe ẹni náà wá sípàdé. (th ẹ̀kọ́ 19) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 4) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ẹ̀kọ́ 01 kókó 6 àti Àwọn Kan Sọ Pé (th ẹ̀kọ́ 9) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Jẹ́ Káwọn Èèyàn Mọ̀ Pé Ayé Tuntun Ò Ní Pẹ́ Dé!”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò orín náà Ayé Tuntun. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 15 ¶8-14 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 34 àti Àdúrà