ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 November ojú ìwé 5
  • November 15-21

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 15-21
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 November ojú ìwé 5

November 15-21

JÓṢÚÀ 23-24

  • Orin 50 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ìmọ̀ràn Tí Jóṣúà Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kẹ́yìn”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Joṣ 24:2​—Ṣé abọ̀rìṣà ni Térà bàbá Ábúráhámù? (w04 12/1 12 ¶1)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Joṣ 24:19-33 (th ẹ̀kọ́ 11)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 2)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 20)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi kókó pàtàkì ní ẹ̀kọ́ 01, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe (th ẹ̀kọ́ 3)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 28

  • Yẹra fún Ẹgbẹ́ Búburú Níbi Iṣẹ́: (7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Yẹra fún Ohun Tó Lè Ba Ìdúróṣinṣin Rẹ Jẹ́​—Ẹgbẹ́ Búburú. Lẹ́yìn náà béèrè pé: Kí ló ṣẹlẹ̀ sí Arábìnrin Kẹ́mi nígbà tó bẹ̀rẹ̀ sí í kẹ́gbẹ́kẹ́gbẹ́ níbiiṣẹ́? Àyípadà wo ni Arábìnrin Kẹ́mi ṣe, báwo nìyẹn sì ṣe ràn án lọ́wọ́? Kí lo rí kọ́ nínú fídíò yìí nípa bó o ṣe lè yẹra fún ẹgbẹ́ búburú?

  • Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ Ní Ibi Tí O Ò Lérò: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè pé: Kí ló ṣẹlẹ̀ sí Akil tó mú kó bẹ̀rẹ̀ sí í bá àwọn ọ̀rẹ́kọ́rẹ̀ẹ́ rìn níléèwé? Báwo ló ṣe rí ọ̀rẹ́ gidi nínú ìjọ? Kí lo rí kọ́ nínú fídíò yìí tá ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti ní ọ̀rẹ́ gidi?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 16 ¶1-8 àti fídíò ohun tó wà ní orí 16

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 39 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́