ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 November ojú ìwé 14
  • December 27, 2021–January 2, 2022

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 27, 2021–January 2, 2022
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 November ojú ìwé 14

December 27, 2021–January 2, 2022

ÀWỌN ONÍDÀÁJỌ́ 13-14

  • Orin 134 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ohun Táwọn Òbí Lè Rí Kọ́ Látinú Ohun Tí Mánóà àti Ìyàwó Rẹ̀ Ṣe”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Ond 14:2, 3​—Kí nìdí tí Sámúsìn fi sọ pé obìnrin ará Filísínì yẹn “lẹni tó yẹ” òun? (w05 3/15 26 ¶1)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ond 14:5-20 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • “Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Máa Dá Kẹ́kọ̀ọ́”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Máa Dá Kẹ́kọ̀ọ́.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi kókó pàtàkì ní ẹ̀kọ́ 02, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe (th ẹ̀kọ́ 17)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 110

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 18 ¶1-8 àti fídíò ohun tó wà ní orí 18

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 148 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́