February 14-20
1 SÁMÚẸ́LÌ 3-5
- Orin 1 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Jèhófà Máa Ń Gba Tiwa Rò”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 1Sa 3:3—Kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé kì í ṣe inú Ibi Mímọ́ Jù Lọ ni Sámúẹ́lì sùn sí? (w05 3/15 21 ¶6) 
- Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Sa 3:1-18 (th ẹ̀kọ́ 10) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ ẹni náà, kó o sì lo ìwé pẹlẹbẹ Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! (th ẹ̀kọ́ 11) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ìwé pẹlẹbẹ Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! kó o sì fi ẹ̀kọ́ 01 bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 15) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ẹ̀kọ́ 03 kókó 6 (th ẹ̀kọ́ 14) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Ohun Tá A Lè Kọ́ Lára Sámúẹ́lì”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tá A Rí Kọ́ Lára Sámúẹ́lì. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 20 ¶9-17 àti àpótí 20A 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 99 àti Àdúrà